Africa Eye wádii àwọn tó wà nídìí ìgbésùmọ̀mí ni Mozambique

Africa Eye wádii àwọn tó wà nídìí ìgbésùmọ̀mí ni Mozambique

Ijinigbe, iṣekupani lọna aitọ, ile ati dukia ẹni didana sun, ati awọn iwa ipa miran lo ti n ṣẹlẹ kaakiri agbaye paapaa ni awọn agbegbe kọọkan lo ti wọpọ julọ.

Lati ọdun 2017 ni oriṣiriṣi nkan ti n ṣẹlẹ ni orilé-ede Mozambique paapaa ni ẹkun Cabo Delgado ni ariwa Mozambique

Iko iwadii Africa Eye BBC ṣe iṣẹ iwadii lori igbesunmọmi ni ẹkun yii.

Wo ibi tí awọn ara ilu ti da awọn agbesunmọmi mọ ṣugbọn ti wọn ko gbọdọ sọrọ.

Láti ọdún mẹ́rin sẹ́yìn ìjọba Mozambiqe ni àwọn kò mọ agbésùmọ̀mí níbẹ̀

Abọ iwadii yii lagbara.