Alaafin stool: Wo ẹni tó ṣeẹṣe pé kí Aláàfin kàn lẹ́yìn ìpapòdà Oba Lamidi Adeyemi

Alaafin stool: Wo ẹni tó ṣeẹṣe pé kí Aláàfin kàn lẹ́yìn ìpapòdà Oba Lamidi Adeyemi

Iwe ofin ẹni ti oye Alaafin kan ti a fẹnuko le lori lọdun 1974 ni ki Ijọba tẹle- Omooba Tijani Atiba.

Bi ọmọ ko ba ba itan, o di dandan ko ba arọba to jẹ baba itan.

Omooba Tijani Adebayo Olawoyin Atiba to jẹ ọkan pataki lara awọn ọmọ Oba Atiba to jẹ Alaafin Oyo nigba aye rẹ ba BBC sọrọ ni kikun lori ona ti wọn fi n yan alaafin ni ilu Oyo.

Baba Agba yii ṣalaye ohun to ṣẹlẹ to fi jẹ pe o to ọdun mẹta leyin ipapoda Alafin mii ki Oba Adeyemi to gab ade nigba naa.

Awọn idile wo ni Oye Alaafin kan lasiko yii?

Omooba Tijani Olawoyin Atiba ṣalaye kikun nipa awọn idile to n jọba ni Oyo.

Iye awọn to ti jẹ Alaafin sẹyin lati inu idile kọọkan ati awọn ti o kan bayii lati jẹ.