Osun Debate: Ó wà nínú ẹjẹ́ mi láti yọ àwọn ará Osun kúrò nínú ọ̀fìn- Lasun Yusuff

Osun Debate: Ó wà nínú ẹjẹ́ mi láti yọ àwọn ará Osun kúrò nínú ọ̀fìn- Lasun Yusuff

O yẹ ki a tún ìwé òfin Naìjíríà ṣe- Lasun Yusuff

Oloye Lasun Yusuff lo n dije dupo gomina ipinle Osun labe ẹgbẹ oselu Labour Party.

O sọrọ ni kikun lori awọn nakn to fẹ ṣe fun awọn eeyan ipinlẹ Osun ti wón ba dibo fun un.