Ile asofin agba buwọlu aba to fofin de tita siga leyọ ẹyọ

Ile asofin agba buwọlu aba to fofin de tita siga leyọ ẹyọ

Adari iponlongo fun ajọ Environmental Rights Action ati ti Friends of the Earth Nigeria (ERA/FoEN) Philip Jakpor, nigba to n ba BBC sọrọ, wipe idunnu lojẹ fun awọn nigba ti awọn asofin agba fọwọsi aba lati fopin si tita siga layika ile-ẹko, ti ko si si eni to tako aba ofin naa.