Awọn to bori, awọn to f'idirẹ'mi ninu Champions League

Alex Sandro ti Juventus Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Harry Kane ti gba bọ̀ọ́lu sinu àwọ̀n fun Tottenham ni saa yii

Tottenham ti pada s'oju opo aṣeyọri pẹ̀lu bi o ṣe ta ọ̀mọ̀ pẹ̀lu Juventus lẹ́yin ipinlẹ to o mẹ́hẹ lasiko ti idije Champions League bẹ̀rẹ̀.

Ikọ̀ Mauricio Pochettino lo kọ́kọ́ gba bọ́ọ̀lu sinu awọ̀n lẹ́ẹ̀meji laarin iṣẹ́jú mẹ́waa ti ifẹ̀sẹ̀wọnsẹ̀ naa bẹ̀rẹ̀ lẹyin ti Gonzalo Higuain gba pẹnariti wọle lati fi ṣe èrè fun fao to wa lati ọdọ Ben Davies nigba ti o ti Federico Bernardeschi ṣubu.

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Man City gba isakoso nigba to ku ọgbọn iṣẹju ki ifẹ̀sẹ̀wọnsẹ̀ naa wa s'opin

Oludari Manchester City, Pep Guardiola gboriyin fun Ilkay Gundogan fun bi o se fakọyọ lasiko ti ikọ Man City gbe igbesẹ akin nipele to wa saaju eyi to kangun si aṣekagba idije ife ẹ̀yẹ Champions League.

Man City gba isakoso nigba to ku ọgbọn iṣẹju ki ifẹ̀sẹ̀wọnsẹ̀ naa wa s'opin.

Awọn ifẹ̀sẹ̀wọnsẹ̀ ti yoo waye loni ni:

Real Madrid vs Paris Saint Germain

FC Porto vs Liverpool

Related Topics