Igbeyawo Ọmọọba Harry ati Meghan Markle nkanlẹkun

Igbeyawo Ọmọọba Harry ati Meghan Markle nkanlẹkun

Iroyin lati aafin Kensington sọ wipe ayẹyẹ igbeyawo naa yoo bẹrẹ nile-ijọsin.

Osu kọkanla ọdun to kọja ni wọn fi kede wipe awọn mejeeji yoo segbeyawo lọdun yii.