Ifọrọwanilẹnuwo pẹlu Ọjogbọn Soyinka
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Wọle Soyinka: Ti mo ba dara pọ m'ẹgbẹ Obasanjọ, wọn gbọdọ yẹ mi lọpọlọ wo

Ọjogbọn Wole Soyinka ba BBC Yoruba sọrọ lori ọrọ oselu ni Naijiria.

Wọn wipe asiko ti to fun awọn ọdọ lati fa enikan lara wọn kale fun ipo adari ni Naijiria, wọn si wipe awọn agbalagba bi ti wọn yoo gbaruku ti iru ẹni bee leyin.

Siwaju si, wọn ni ki awọn agbalagba lọ wa bi joko si ki awọn ọdọ le raye sejọba.

Soyinka: Ti mo ba dara pọ mọ ẹgbẹ Obasanjọ, wọn gbọdọ yẹ mi lọpọlọ wo

Bakana lori leta oloye Ọbasanjọ̀ ati ogagun Babangida, Soyinka sọ wipe o yẹ̀ ki awọn eniyan maa funra ti awọn ologun ba ti n kọlẹta si ara wọn.

Awọn iroyin ti ẹ lee nifẹẹ si: