Gani Adams: Ẹni ba fe pẹ laye, maa ra aye gbe ni

Gani Adams: Ẹni ba fe pẹ laye, maa ra aye gbe ni

Aarẹ Ona Kakanfo ilẹ Yoruba, Otunba Gani Adams ni ifọrọwanilẹnuwo pẹlu BBC Yoruba.

O sọ wipe kii ṣe ootọ pe awọn to ba jẹ oye Aarẹ Ona Kakanfo kii pẹ laye.

Awọn iroyin ti ẹ lee nifẹẹ si: