Mori ara mi to funfun, mi o mọ pe ẹtẹ ni
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Tunji: Kàyééfì ni bí mo ṣe dẹ́tẹ̀; mo ń gbé ibí pẹ̀lú àwọn 137 míì

Mo ṣi máa ń jáde lọ si ọjà, báńkì àti káàkiri ti ààyè bá wà.

Tunji Oluwatimilehin ba BBC Yoruba sọrọ nipa iriri rẹ gẹgẹ bi adẹtẹ àti ìgbé ayé gbogbo àwọn mẹtadinlogoje ti wọn n gbe ni 'Lepers Colony' nipinlẹ Ondo ni Naijiria.

Aisan ẹ̀tẹ̀ ni àwọn kan gba pe o léwu lati gbe pẹlu awọn ti kò ní i, eyi to ṣokunfa bi àwọn adẹ́tẹ̀ ṣe lọ maa n dagbo gbe papọ.

O mẹnuba iranlọwọ omi ti wọn ti ri gbà àti ìlépa wọn ni Ondo.

Awọn iroyin ti ẹ lee nifẹẹ si: