Food Day: Ẹwa Agọnyin jẹ aayo ounjẹ Badagry

Food Day: Ẹwa Agọnyin jẹ aayo ounjẹ Badagry

Ẹwa Agọnyin jẹ ounjẹ to gbajugbaja nilu Badagry, amọ o di aayo kaakiri awọn ilu nlanla nilẹ kaarọ oojire.

Ẹwa Agọnyin yi, ti wọn mọ si ẹwa 'Tosẹ' laarin awọn Egun nilu Badagry ni ọpọ ọmọ Yoruba tun nifẹ si lati maa jẹ.

Ẹwa Agọnyin yi ni wọn lo n f'ara lokun to si dara fun eroja asara loore.