Kini itumọ ‘International passport’ l'ede Yoruba?

Kini itumọ ‘International passport’ l'ede Yoruba?

BBC Yoruba ko fẹ ki ede Yoruba parun ni iran yii ni a ṣe maa n ran ara wa leti awọn ọrọ kan ki a le tumọ rẹ fun ara wa.

Loni, itumọ International Passport ni a fẹ kọ ara wa ni ede Yoruba.

Itumọ "international passport" l'ede Yoruba ni iwe irinna Agbaye.

Awọn iroyin ti ẹ lee nifẹẹ si: