Ọjọgbọn 'Bisoye Ẹlẹsin ni o yẹ ka kọ ọmọ l'ede Yoruba
Ọjọgbọn 'Bisoye Ẹlẹsin ni o yẹ ka kọ ọmọ l'ede Yoruba
Ọjọgbọn 'Bisoye Ẹlẹsin ti parọwa fun awọn ọmọ kaarọ oojire lati maa kọ awọn ọmọde ni ede Yoruba.
O sisọ loju rẹ pe awọn oyinbo ti nkọ ede Yoruba bayi ki wọn lee pada wa kọ awọn ọmọ wa.