Idibo 2019: Aawọ abẹnu lee koba APC

Idibo 2019: Aawọ abẹnu lee koba APC

Ọmọwe Dikrullahi Yagboyaju ti woye pe aawọ abẹnu ninu ẹgbẹ APC lee koba ẹgbẹ naa ninu ibo ọdun 2019.

Ọmọwe Yagboyaju woye ọrọ yi lasiko to n sọrọ pẹlu ikọ BBC Yoruba.

O fikun pe agba ọjẹ ni Oloye Ahmed Bọla Tinubu ti wọn fi se asaaju igbimọ to n pẹtu saawọ ninu APC.

to si da oun loju pe yoo sisẹ takuntakun lati saseyọri.