Seyi Law ni 2009 loun ni miliọnu akọkọ
Seyi Law ni 2009 loun ni miliọnu akọkọ
Gbajugbaja adẹrin posonu, Seyi Law sọ pe ọdun 2009 ni oun ti ni miliọnu akọkọ oun.
Bakanaa lo tun sọ iriri rẹ gẹgẹ bii apanilẹrin ati bo se ni miliọnu akọkọ rẹ.
Seyi Law tun mẹnuba ọpọ nkan to tun yii pada si eniyan ọtọ.