Agbẹdẹ Adodo
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ibadan ni agbẹdẹ akọkọ wa - Idile Adodo

Idile Adodo ni awọn ni agbẹdẹ akọkọ ni iwọ oorun guusu Naijiria, bẹẹ si ni idile wọn lo ma n rọ ibon ati ọta fun awọn jagunjagun latijọ.

Iru awọn iroyin ti ẹ le nifẹsi: