Aarẹ Ona kakanfo, Iba Gani Adams: Ẹèyàn máa ń ra ayé gbé ni, ọ̀tá kò fẹ́ kí ẹnìkankan gbé ilé ayé se rere

Aarẹ Ona kakanfo, Iba Gani Adams: Ẹèyàn máa ń ra ayé gbé ni, ọ̀tá kò fẹ́ kí ẹnìkankan gbé ilé ayé se rere

Aarẹ Ona Kakanfo so wi pe ko si ẹni ti ko ni ku, sugbọn ẹni ba maa pẹ laye maa ra aye gbe ni.

Iba Gani Adams salaye fun BBC Yoruba pe Olorun lo ni okun ẹ̀mí lọ́wọ́.

Ati pe ko kuku si eni ti ko ni ku laye sugbon asiko lo yatọ si ara wọn.

Kini Gani Adams pe ni ọ̀na abayọ?

Aare Ona Kakanfo gbogbo ile Yoruba lasiko yii, Iba Gani Adams sọ̀rọ̀ lori ona abayo pe aragbe ni ile aye.

O ni bi eeyan ba se sunmo awon ti Olodumare gbe aye le lọ́wọ́ to ni o ku si iru eni bẹ́ẹ̀ lọ́wọ́.

Ati pe ki onikaluku ma sun asunpara.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: