Ilu gangan: O jẹ́ atọ́nà fún Alaafin àti àwọn ara ilu- Rahman Wahab

Ilu gangan: O jẹ́ atọ́nà fún Alaafin àti àwọn ara ilu- Rahman Wahab

Ọtun onilu Alaafin Ọyọ ti salaye awọn ohun to rọ mọ ilu gangan

Bakan naa lo tun sọ isẹ ti ilu ọhun n se ati awọn iwulo rẹ fun Alaafin ati awọn ara ìlú paapaa ni kikun.

Awọn iroyin ti ẹ lee nifẹẹ si:

Ogbẹni Rahman Wahab ṣalaye pe atọna ni ilu jẹ fun tẹru tọmọ, o tun jẹ akilọ iwa to si tun n ta ni lolobo.

O sọ pataki ṣaworo to wa leti ilu ti kii ba wọn re ode ibanujẹ pẹlu ṣẹkẹrẹ.