‘ Awọn ọmọ Yobe’: Ibeere mẹrin to n ja ranyinranyin

Awọn ọmọ ileewe joko ni gbọngan nla Image copyright Yobe state governmentt
Àkọlé àwòrán Ko si ẹni to lee sọ ibi pato ti awọn ọmọ ileewe Yobe wa bayii

Titi di bi a se n sọrọ yii,ko tii si aseyọri kan pato lori awari awọn ọmọ ileewe Girama ẹkọsẹ ọwọ awọn obinrin nilu Dapchi ni ipinlẹ Yobe lẹyin isẹlẹ to sẹ ni ọjọ aje nibiti awọn akẹkọ ileewe naa kan ti di awati.

Amọsa ni bayii awọn ibeere kan ti n ja ranyinranyin kaakiri.

Eni- Se wọn yoo di ohun elo ado oloro fun ikọ Boko haram ni?

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Se wọn yoo di ohun elo ado oloro fun ikọ Boko haram ni?

Eji- Se awọn naa yoo di ohun elo pasipaarọ laarin ijọba ati Boko Haram ni?

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Se awọn naa yoo di ohun elo pasipaarọ laarin ijọba ati Boko Haram ni?

Ẹta- Se awọn naa yoo di aya tipatipa fun awọn agbesunmọmi Boko Haram ni?

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Se awọn naa yoo di aya tipatipa fun awọn agbesunmọmi Boko Haram ni?

Ẹrin-Se awọn ọmọbinrin ti wọn ji gbe yii yoo lee pada si ileewe mọ?

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Se awọn ọmọbinrin ti wọn ji gbe yii yoo lee pada si ileewe mọ?