Omo Ibadan coaching center bá iléeṣẹ BBC lálejò, ẹrín ń pé èrín rán níṣẹ
Omo Ibadan coaching center bá iléeṣẹ BBC lálejò, ẹrín ń pé èrín rán níṣẹ
Itumọ BBC ti a mọ ko ba ti ọmọ Ibadan mu. E gbo bi o se salaye BBC tirẹ.
Lizzy Jay to jẹ adẹrinposọnu to n ṣakoso ọmọ Ibadan coaching center sọ bo to lọrọ, ẹ fun oju lounjẹ ayọ ninu fọnran fidio yii...