Isẹ asayẹyẹ f'oku
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Oku o kii n ba mi lẹru

Ọmọbinrin asaraloge to wa di asayẹyẹ f'oku leyin ti baba ati aburo rẹ ku ninu ijamba ọkọ ofurufu nigbati awọn naa fẹ lọ sayẹyẹ f'oku.

Iru awọn iroyin ti ẹ nifẹ si: