Eko: Ọja Alaba njona

Aworan ina kan to jo ri nipinlẹ Eko

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Ọja Alaba to wa nipinlẹ Eko n jona lọwọ bayii.

Ẹnikan ti isẹlẹ ina naa soju rẹ sọ fun ileesẹ BBC Yoruba wipe ibudo ikerusi lo n jona ninu ọja naa.

Ọja naa to jẹ ọkan lara awọn ọja to tobi ju nipinlẹ Eko.

Awọn iroyin ti ẹ lee nifẹẹ si: