Idibo sipọ aarẹ ati ile igbimọ asofin n waye ni Sierra Leone

Idibo sipọ aarẹ ati ile igbimọ asofin n waye ni Sierra Leone

Awọn ọmọ orilẹede Sierra Leone to le ni miliọnu mẹta n dibo yan aarẹ lọjọ keje, osu kẹta ọdun yi.

Awọn iroyin ti ẹ lee nifẹẹ si: