Bode George s'ọrọ lori abadofin tuntun ipinlẹ Eko

Oloye Bọde George bu ẹnu ẹtẹ lu aleekun owo ori lori ile ati ilẹ nipinlẹ Eko. O sọ wipe ara n ni awọn eniyan.