'Obinrin jẹ amuludun'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Igbakeji gomina Eko sọrọ nipa obinrin

Arabinrin Idiat Adebule to jẹ igbakeji gomina ipinlẹ Eko so wipe amuludun ni obinrin jẹ. Siwaju si, o wipe obinrin jẹ ẹni to le boju to ohun gbogbo.

Iru awọn iroyin ti ẹ le nifẹ si: