Wo ẹsa ninu aworan Afrika lọsẹ yii: 2-8 osu keta ọdun 2018

Ẹsa ninu awọn aworan to rewa ju kakiri ilẹ Afrika ati ti awọn ọmọ Afrika nibomiran lagbaye lọse yii.

Members of Kenya Girl Guides take photos after attending ceremony of the International Women"s day at Kawangware in Nairobi, Kenya, on March 8, 2018 Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Awọn ọmọbirin orilẹede Kenya ti wọn jẹ ọmọ ẹgbẹ Girl Guides wa lara awọn miliọnu-miliọnu awọn eeyan lagbaye ti wọn ṣẹ ayeye ayajọ ọjọ obirin agbaye l'Ọjọbọ.
Awọn ololufẹ ẹgbẹ agbabọọlu kan nilẹ Kenya, Gor Mahia, wọn dunnu lori ọkọ akero ti wọn pe ni matatu lẹyingba ti ẹgbẹ wọn koju ẹgbẹ agbabọọlu Tunisia, Esperance, ninu idije CAF Champions League ni Machakos,lorilẹede Kenya, lọjọ keje osu kẹta ọdun 2018. Image copyright EPA
Àkọlé àwòrán Awọn ololufẹ ẹgbẹ agbabọọlu kan nilẹ Kenya, Gor Mahia, wọn min pada sile pẹlu ara lẹyin igba ti wọn wo bi ẹgbẹ wọn ṣe koju ẹgbẹ agbabọọlu kan lati ilẹTunisia, Esperance, ninu idije African Champions League. Odo sodo nifẹsẹwọnsẹ naa pari.
Ẹgbẹ agbabọọlu Al Ahly tilẹ Ijibiti ati ẹgbẹ agbabọọlu CF Mounana tilẹ Gabon wọn wako ni papa ere bọọlu Cairo to wa ni Ijibiti Image copyright Reuters
Àkọlé àwòrán Bakanaa, ololufẹ ẹgbẹ agbabọọlu kan ni Ijibiti, Al Ahly, tanna si papa ẹrẹ bọọlu to wa ni igboro Cairo nigba ti ẹgbẹ rẹ f'agbahan ẹgbẹ agbabọọlu kan ni Gabon, Mounana, pẹlu ami ayo mẹrin sodo.
Cameroonian (orange) and Senegalese (yellow) African migrants, split into two teams, take part in a football match at the Libyan Interior Ministry's illegal immigration shelter in Tajoura, Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Wọn gba ifẹsẹwọnsẹ yii ninu ọgba ẹwọn kan ti wọn ko awọn atipo si ni lorillẹede Libya. Wọn gba ifẹsẹwọnsẹ naa ni laarin awọn ọmọ orilẹede Senegal ati awọn ọmọ orilẹede Cameroon.
A member of Kenyan acrobat group Kibera Messenger breathes fire during a performance for filming in Kibera, Nairobi, on March 7, 2018. Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Arabirin ilẹ Kenya yii in fi ina sere ladugbo Kibera ni olu ilu orilẹede naa, Nairobi, l'Ọjọru (Wednesday).
Two young Dambe boxers fight in Lagos on 2 March 2018. Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Awọn ẹlẹṣẹ ariwa Naijiria yii n dan agbara wọn wo ni igboro Eko. Ẹṣẹ dambe jẹ irufẹ ija kan to ko laanu to wopọ laarin awọn ẹya Hausa
Lupita Nyong'o attends the 2018 Vanity Fair Oscar Party hosted by Radhika Jones at Wallis Annenberg Center for the Performing Arts on March 4, 2018 in Beverly Hills, California. Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Oṣiṣe tiata orilẹede Kenya, Lupita Nyong'o, fi okun wura dara si ori rẹ gẹgẹ bi aṣa awọn ara Rwandan nigba ajọyọ Oscar l'ọjọ Aiku.
Said, 43, removes snow with a shovel around his vehicle stuck in the snowy and twisty roads, 60km from Azilal city, central Morocco, 05 March 2018 (issued 07 March 2018). Azilal is a city in central Morocco, in the Atlas Mountains, Image copyright EPA
Àkọlé àwòrán Isesi oju-ọjọ yi to mu otutu pupọ wa ṣẹlẹ ni nitori "ẹranko kan to wa lati ila oorun" eleyi to gba iwo-oorun Yuroopu l'ọsẹ yii. O jẹ ki yinyin bọ lori awọn oke Atlas ni orilẹede Morocco.
Internally displaced Congolese return to the shore line of lake Albert after spending the night out in the lake for safety on March 05, 2018 in Tchomia. Displaced Congolese, fleeing inter-communal violence in the Ituri region of the Democratic Republic of the Congo, make their way to the Tchomia on the DRC side of Lake Albert in search of safety and boats to make the crossing to the safety of the refugee camps in Uganda Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Ẹbi yii jẹ ọkan lara awọn ẹgbẹgbẹrun ẹniyan ti wọn sa asala kuro nibi rogbodiyan ila oorun orilẹede DR Congo, wọn lo ọkọjuomi lati rekoja lori adagun omi Lake Albert ni orilẹede Uganda.
Gold prospectors work in the Pampana river on March 5, 2018 near Mekeni, northern Sierra Leone. Down a dirt road that slopes off a bridge, hundreds of men and women waist-deep in the river sift through gravel, separating specks of gold from the sludge. It may be the eve of a general election in Sierra Leone, but those who eke out a living here in Magburaka have few expectations from a new government, whichever party wins Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán L'ọjọ Aje, awọn okunrin ati awọn obirin yii ni orilẹede Sierra Leone n tẹpa mọsẹẹ yiyọ wura ninu yanrin nigboro Makeni to wa ni ariwa orilẹede naa.
Anti riot policeman drags away a supporter of Sierra Leone People"s Party (SLPP) during a protest against the police attempting to search the offices of Julius Maada Bio, the presidential candidate for (SLPP) in Freetown, Sierra Leone March 7, 2018. Image copyright Reuters
Àkọlé àwòrán Wọn dibo Ọjọru lorilẹede naa jẹẹjẹẹ - lai si wahala kankan to ju ifẹhonuhan lọ ni waju ileesẹ ẹgbẹ alatako Sierra Leone People's Party (SLPP), nibi ti wọn ti mu ọkunrin yii.
Protestors carry coffins as they wave placards during a rally in front of the morgue of Yopougon University Hospital in Abidjan on March 7, 2018, as they stage a protest against IVOSEP - the dominant funeral service provider in Ivory Coast. Hundreds of small undertaker firms in Ivory Coast have gone on strike over what they described as abusive practices by the country's dominant funeral company. Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Ni orilẹede Ivory Coast, awọn ti wọ sinku ni wọn fẹhonu han lori nkan ti wọn pe ni iwa ai ṣe dede ti ileeṣẹ sinku-sinku to tobi ju lọ lorilẹede naa n ṣe.
Eritrean migrants pose for a group photograph after being released from the Holot detention facility (rear) near Nitzana in the Negev Desert in Israel, 06 March 2018. The African, from Eritrea and Sudan are among some 100 African immigrants Israel is releasing as they clear the prison ahead of its closure. Image copyright EPA
Àkọlé àwòrán Awọn atipo orilẹede Eritrea kan ni ilẹ Israel duro lati ya fọto nigba ti wọn kuro ni ogba ẹwọn Holot ninu Israel.

Orisun awọn aworan naa ni AFP, Reuters, EPA ati Getty Images

Related Topics