PDP wipe APC ti ku'na lati gbogun t'iwa ibajẹ

Akọwe ipolongo PDP, Kola Ologbodiyan sọ pe ẹgbẹ APC ati ijọba Aarẹ Muhammadu Buhari ni jẹgudu jẹra ni Naijiria.