Yollywood òṣèrè, Dayọ Amusa: Ko si eni ti ko ni baba isalẹ
Yollywood òṣèrè, Dayọ Amusa: Ko si eni ti ko ni baba isalẹ
Osere tiata Dayo Amusa gboriyin fun awọn to n parọ, o ni isẹ ribiribi ni wọn n se.
Lasiko to n ba BBC Yoruba lalejo lo ti mẹnuba pataki Baba Isalẹ ati irufẹ ajọṣepọ to yẹ ko wa laarin wọn.