'Awọn eeyan a dibo fun wa lọdun 2019'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Bolaji Abdulahi: Awọn eeyan a dibo fun wa lọdun 2019

Agbẹnusọ fun ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC) sọ fun BBC wipe ẹgbẹ oṣelu naa mọ wipe lootọ nkan nira diẹ bayi pẹlu ijọba yi, ṣugbọn awọn gbagbọ wipe awọn eniyan yoo dibo fun ẹgbẹ naa leekeji lọdun 2019.

Awọn iroyin miran ti ẹ le nifẹ si: