Wo fidio ikede iku Hawking to ku lẹni ọdun mẹrindinlọgọrin (76)

Wo fidio ikede iku Hawking to ku lẹni ọdun mẹrindinlọgọrin (76)

Fidio ikede iku Hawking to ku lẹni ọdun mẹrindinlọgọrin (76) - Ọmọ ilẹ Gẹẹsi ti amọ nipa iṣẹ rẹ lori iho dudu ati ọgbọn atinuda, o si kọ awọn iwe to gbajugbaja bii "Itan asiko diẹ.'