Ina sọ nibudo idalẹsi Olusosun-Ọjọta
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ina: Ibudo idalẹsi Olusosun-Ọjọta njona

Ina sọ nibudo idalẹsi to wa ni Olusosun ladugbo Ọjọta nilu Eko nirọlẹ ọjọru.

Se ni eefin gba oju ọrun kan, ti gbogbo adugbo naa si dudu fun eefin.

Ọkọ panapana kan si ti wa nikalẹ lati pa ina naa ko maa baa mu ijamba to pọ lọwọ