RRS : Ẹwa gbe igbo yin

Aworan ogun oloro Image copyright TWITTER/RRS LAGOS
Àkọlé àwòrán O to ọjọ mẹta ti RRS ti'n dẹgun le awọn to n ta ogun oloro nipinlẹ Eko

Ikọ ọlọpa kogberegbe ilu Eko, RRS, ti polongo ki awọn to ni'gbo lọdọ awọn tabi eni to ba mo ẹni to lẹru igbo ko sọ fun wọn ki wọn wa gbẹru wọn.

Ọrọ na yayin lẹnu bii?

Loju opo twita wọn ni wọn fi ikede naa si.

Wọn ni eyi ti awọn ẹru ti awọn gba lọwọ awọn to'n ta ogun oloro naa se lọdọ awọn to gee ki ẹnikẹni to ba mọ awọn to ni ẹru naa sọfun wọn pe ki wọn wa gbẹẹru wọn.

Awọn ọmọ Naijiria ko jafara lati fọ esi fun wọn.