Qatar jẹ ibi ti ọpọ ọmọ ilu sanra kọja ala

Qatar jẹ ibi ti ọpọ ọmọ ilu sanra kọja ala

Lorilẹẹde Qatar iye ọmọ ilu to sanra koja ala peleke. Ijọba ni oun setan lati gbe igbesẹ ti yoo mu adinku ba iye wọn pẹlu sise ayẹwo fun awọn to ni aisan itọ ṣuga.

Iru awọn iroyin ti ẹ le nifẹ si: