FRSC o gbọdọ ni ju 500 naira lọwọ
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ẹṣọ oju-popo ti a ba ri ju 500 naira lọwọ re wọ gau

Ọga awọn ẹṣo alaabo oju popo kan ti ke si awọn ọlọkọ ati awọn arinajo wi pe ki wọn pa ofin ọna mọ. O tun sọ wipe ẹsọ oju-popo ti o ba mu ju 500 naira lọwọ setan ati wọ wahala ijọba.

Iru awọn iroyin ti ẹ le nifẹ si: