BBC ṣe'filọlẹ Yoruba, Igbo ati Pidgin
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

BBC: A nko oju opo BBC Yoruba, Igbo ati Pidgin jade

Awọn oju opo BBC tuntun mẹtẹẹta yii ni yoo maa mu iroyin atigbadegba wa setigbọ awọn ọmọ Naijiria ni ede Yoruba, Igbo ati Pidgin.

Oludari agba fun BBC lẹkun Afrika, Solomon Mugera ati Toyosi Ogunsẹyẹ, tii se oludari BBC lẹkun iwọ oorun Afrika wipe awọn oju opo yii yoo maa gbe asa, ede ati ise awọn ẹya mẹtẹẹta larugẹ.

Iru iroyin ti ẹ le nifẹ si: