Wọle Ṣoyinka: Owe maa n ran mi leti MKO Abiọla

Wọle Ṣoyinka: Owe maa n ran mi leti MKO Abiọla

Bọtilẹ jẹ pe Gẹẹsi l'aye mọ mọ ọjọgbọn Wọle Ṣoyinka, ibeere nipa owe Yorùbá ko ba onkọwe naa l'ojiji.