Ọmọ Ibadan: Ọpọlọpọ eeyan ro pe n ko gbọ Gẹẹsi

Ọmọ Ibadan: Ọpọlọpọ eeyan ro pe n ko gbọ Gẹẹsi

Gbaugbaja apanilẹri nni, Adeyẹla Adebọla, ti gbogbo eeyan mọ si ọmọ Ibadan, s'alaye fun BBC Yoruba pe oun ko kọla s'oju b'awọn eeyan kan ṣe lero.

Lẹyin igba naa lo ba BBC ṣe 'idanilẹkọ' diẹ.