Ọpọ pasitọ ati Alfa di oloṣelu - Ladọja
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ladọja: Ọpọ pasitọ ati Alfa ti di oloṣelu

Rashidi Ladọja sọ fun BBC wipe oun ko ti f'ẹyinti nibi oselu, ati wipe awọn pasitọ ati awọn lemaamu naa ti di oloselu.

Bakanaa lo tun se ẹkunrẹrẹ alaye nipa idi to fi wọ gomina ipinlẹ Ọyọ, Sẹnetọ Abiọla Ajimọbi lọ sileẹjọ.

Iroyin ti ẹ lee nifẹ sii: