Tóyìn Adégbọlá: Kò yẹ kí obìnrin fi ìdí gba ipò tíátà

Tóyìn Adégbọlá: Kò yẹ kí obìnrin fi ìdí gba ipò tíátà

Ìlùmọ̀ọ́ká òsèré tíátà kan, Yèyé Tóyìn Adégbọlá ti késí àwọn akẹẹgbẹ́ rẹ̀ lóìinrin àti àwọn aráàlú tó bá ní ìfẹ́ láti di òsèré orí ìtàgé láti m''ase gbé ara wọn sílẹ̀ fún ọkùnrin kankan, kí èròǹgbà wọn tó leè jọ.

Yèyé Tóyìn Adégbọ, tí gbogbo èèyàn tún mọ̀ sí Asẹ́wó tó re Mecca, lásìkò tó ń bá BBC Yorùbá sọ̀rọ̀ ní ipa kan tó kó nínú eré ni wọ́n se ń pèé ní Asẹ́wó tó re Mecca àmọ́ ní báyìí, òun ti yíi padà sí Asẹ́wó tó re London.

Awọn iroyin ti ẹ lee nifẹẹ si: