Báwo lẹ se gbọ́ òwe sí ?
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Àwọn ọmọ Yorùbá àtàtà: Báwo lẹ se gbọ́ òwe sí ?

BBC Yorùbá fọ̀rọ̀ wá àwọn ọmọ Yorùbá àtàtà lẹ́nu wò nípa bí wọ̀n se gbọ́ òwe sí.

Bákanáà la tún bi wọ́n láti kọ orin ìbílẹ̀ wa kan tí wọn bá mọ̀.

Awọn iroyin ti ẹ lee nifẹẹ si: