Ó yẹ kí Nàíjíríà lo igbó fún ìwòsàn
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Onímọ̀ kan ńfẹ́ kí Nàíjíríà lo igbó fún ìwòsàn

Onímọ̀ kan nípa ìdènà àwọn òògùn olóró ti dá àbá pé kí orílẹ̀èdè Nàíjíríà máa igbó fún ìwòsàn .

Onitọ̀ún tó fẹ́ ka fi orúkọ bo òun ní àsírí sàlàyé pé, kò sí ohun tó burú nínú àbá tí àjọ ìsọ̀kan àgbáyé dá n\aà.