Koko iroyin: Awuyewuye àbẹ̀wò Buhari, Ikọlù Zamfara

Eyi ni awọn akojọpọ iroyin ti toni.

Ẹnu kun ìjọba Èkó lori àbẹ̀wò Buhari

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán,

Ipade laarin Tinubu, Akande ati Buhari ti fa oniruuru awuyewuye lẹsẹ

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán,

Àwọn ọlọpa kun gbogbo popona Ilu Eko

Àarẹ Muhammadu Buhari ti orílẹ̀èdè Naijiria ti gúnlẹ̀ sí ìpìnlẹ̀ Èkó fún àbẹ̀wò ẹnu iṣẹ́ ọlọ́jọ́ meji.

Lọ́gán tó dé sí ìlú Èkó ló ṣí ibùdókọ̀ tuntun kan tó wà ni Ikẹja, kó tó di pé ó gbéra lọ si ibi ìdánilẹ́kọ̀ọ́ pàtàkì tó n wáyé fún ayẹyẹ ọja ìbí Asiwaju Bọla Tinubu.

Ẹ̀nìyàn 60 kú nínú ìkọlù Zamfara

Àwọn òlùgbè abúlé kan ní ìwọ̀ àríwá ìpínlẹ̀ Zamfara ti sọ fun BBC wípé ọgọ́ta ènìyàn ló pàdánù ẹ̀mí wọn nínù ìkọ̀lù lẹ́ẹ̀mẹ́ta láàárín ọjọ́ méjì láti ọwọ́ àwọn darandaran lágbèègbè náà.

Ilé isẹ́ ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ náà sọwípé lóòtọ́ ni ìsẹ̀lẹ̀ náà sẹlẹ̀ sùgbọn ènìyàn mẹ́ta làwọn rí òkú rẹ́ nígbà tí àwọn dé ibi ìsẹ̀lẹ̀ náà.

Awọn nkan miran ti ẹ ni lati mọ loni

Gbọ iroyin iṣẹju kan BBC

Fidio wa fun toni

Ọjà Mákòókó : Ibẹ̀ ni ọba ẹja wa ní Èkó

Àkọlé fídíò,

Ọjà Mákòókó : Ibẹ̀ ni ọba ẹja wa ní Èkó