Ẹ̀ṣà ninú àworán Afrika: làáàrin 23-29 oṣu kẹta 2018

Ẹ̀ ṣà ninú àwọn àworán Afríkà àti ti ọmọ Afríkà to rẹwà jù l'agbayé l'ọṣẹ̀ yíi.

Arabìnrín kan ń jọ ni wajú àsìà kan ni Cairo Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán L'ọ́jọ́ Ìṣẹgun (Tuesday) ọ́jọ́ kéjì ibó aàrẹ ilẹ́ Ijíbítì, arabìnrín kan n jọ l'abẹ́ àsià kan ni Cairo...
ọkùnrin Sufi kan to ń pòyì l'adugbó íwò-oòrun Giza Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Tití ọ́jọ́ kejí wọn si ń jọ - sùgbọn ọkùnrin Sufi kan to ń pòyì ni
Ológun ilẹ́ Ijibítì kan duró ni wajú ibùdibo kan ni Cairo,l'ọjọ kejìdílọ́gbọn oṣu kẹta, ọdún 2018. Image copyright Reuters
Àkọlé àwòrán Sugbọn áàbo pọ̀ ju nibi ìbò náà. Àwọn alatákò pàtàkì kò kopa ninu ìbò náà.
Àwọn eèyan n dunú ni wajú ile ẹjọ nla ni ìlú Freetown ni Sierra Leone l'ọjọ kẹrindinlogun oṣu kẹtá ọdún 2018 Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Ni ìdà kejí Afríkà, àwọn eèyan n dunú ni wajú ile ẹjọ nla lẹyín ídajọ́ tó ni kí wọn máa ba ìbo ọjọ́ Àbamẹ́tá lọ ni orílẹ́edẹ́ Sierra Leone...
Arabirin kan duro láàárin awọn ẹranko nigba to ń wa nńkan to dára ní inú àkitàn ni ilú Freetown lọjọ́ kejìdinlọ́gbọ̀, oṣù kẹ̀ta, ọdún, 2018. Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Àwọn olùdibo yóò máa ro nńkan ti àwọn ti wọn ń du ipò náà yóò ṣe lati ṣatunṣe lori ọrọ ajẹ́ orílẹ̀ede náà.
àwọn oni ijọ́ ìbilẹ́ wọn jo nibi ayẹyẹ́ o-da-bọ̀ fun aàrẹ Botswana to fẹ sọ̀kalẹ̀ l'ọjọ́ Àbamẹ́ta Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán L'ọjọ́ Ìṣẹ́gun (Tuesday) ,àwọn oni ijọ́ ìbilẹ́ wọn jo nibi ayẹyẹ́ o-da-bọ̀ fun aàrẹ Botswana to fẹ sọ̀kalẹ̀ l'ọjọ́ Àbamẹ́ta (Saturday)...
... obìnrin kan bu s'ẹkun nibi ìwọde kan ni abulé rẹ̀, Serowe. Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán ... obìnrin kan bu s'ẹkun nibi ìwọde kan ni abulé rẹ̀, Serowe.
L'Ọ́jọ́rú (Wednesday), olóṣèlu, Hassan Ayariga, gun ẹ́ṣin ni olú ilu Ghana, Accra, ninú ìwọdé lorí ìròyìn pe ológun Amerika le bẹ̀rẹ sii lo Ghana gẹgẹ bii ibudo. Image copyright EPA
Àkọlé àwòrán L'Ọ́jọ́rú (Wednesday), olóṣèlu, Hassan Ayariga, gun ẹ́ṣin ni olú ilu Ghana, Accra, ninú ìwọdé lorí ìròyìn pe ológun Amerika le bẹ̀rẹ sii lo Ghana gẹgẹ bii ibudo.
L'Ọ́jọbọ̀ (Thursday), kurúkùrú bó olú ìlú Sudan, Khartoum, nńkan to mu ki ìjọba da baálu duró ki wọn sì ti ilé ìwe Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán L'Ọ́jọbọ̀ (Thursday), kurúkùrú bó olú ìlú Sudan, Khartoum, nńkan to mu ki ìjọba da baálu duró ki wọn sì ti ilé ìwe
L'ọjọ́ Ẹtì (Friday), kẹ̀kẹ́ Maruwa kan fónká nibi tí ado olóro kan ti dún láàárin ọ̀pọ̀ eèyan nigboró Mogadishu, Somalia. Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán L'ọjọ́ Ẹtì (Friday), kẹ̀kẹ́ Maruwa kan fónká nibi tí ado olóro kan ti dún láàárin ọ̀pọ̀ eèyan nigboró Mogadishu, Somalia.
L'Ọjọ́ kan náà ni ìgboro Beijing, àwọn ọmọ ile-iwe duro latí ki aàrẹ Namibia, Hage Geingob. Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán L'Ọjọ́ kan náà ni ìgboro Beijing, àwọn ọmọ ile-iwe duro latí ki aàrẹ Namibia, Hage Geingob.
L'Ọjọ́ (Wednesday),agbábọ́ọ̀lú Krikẹ̀t ilẹ Australia alábukù n nì Steve Smith o n kúrò ni South Africa lẹyin ìgbà to di mimọ̀ wi pe ó ba bọ́ọ̀lù jẹ́ nigba to n erẹ́ láàárin orílẹ́ede mejẹ́jì. Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán L'Ọjọ́ (Wednesday),agbábọ́ọ̀lú Krikẹ̀t ilẹ Australia alábukù n nì Steve Smith o n kúrò ni South Africa lẹyin ìgbà to di mimọ̀ wi pe ó ba bọ́ọ̀lù jẹ́ nigba to n erẹ́ láàárin orílẹ́ede mejẹ́jì.
L'ọjọ́ Àìku (Sunday) ídije eré bọ́ọ̀lú Rugby l'órílẹ́ede Kenya lo da àwọn eleyi pọ. Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán L'ọjọ́ Àìku (Sunday) ídije eré bọ́ọ̀lú Rugby l'órílẹ́ede Kenya lo da àwọn eleyi pọ.
Niparí àwọn ọmọkunrin ń gba bọ́ọ̀lu ni aṣálẹ gúúsú Morocco l'ọjọ ayẹyẹ ajọ̀dun àwọn darandaran Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Niparí àwọn ọmọkunrin ń gba bọ́ọ̀lu ni aṣálẹ gúúsú Morocco l'ọjọ ayẹyẹ ajọ̀dun àwọn darandaran

Orisun àwọn àworan AFP, Reuters, EPA ati Getty Images.

Ní àyíká BBC