Oluwo Ìwo ṣ'àlàye lori oye Emir

Oluwo tilu Iwo
Àkọlé àwòrán,

Oluwo tilu Ìwo sọ pe òun fẹ di Ọba onilawani (Emir) ilẹ Yorùbá

Oluwo ti ilu Ìwo, Oba AbdulRasheed Akanbi, ṣ'àlàyé nńkan to fáà to fi jẹ́ oye Emir.

Oba ọ̀hun sọ pe oun ṣe bẹ́ẹ̀ ni nitori èdè-àìyedè to wà láàárin àwọn oba aladé nilẹ Yorùbá.

Nigbà to ń ba akòròyìn BBC s'ọ̀rọ̀, Oba Àkanbi sọ wipe áàwọ to wa láàárin àwọn oba ipinlẹ Ọ̀ṣun lo faà ti wọn ko tíi ṣe ìpade fun ọdún meji.

Oba náà si sọ pe ọmọ Yoùbá l'oun jà fún.

Ẹ tẹti si ìfọ̀rọ̀wanilẹnuwò pẹlu Oba Àkanbi nibi:

Àkọlé fọ́nrán ohùn,

Oluwo Ìwo ṣ'àlàye lori oyé oba oni lawàni