Èkó: Àwọn akínkánjú obìnrín tó ń wa Márúwá

Èkó: Àwọn akínkánjú obìnrín tó ń wa Márúwá

Àwọn obìnrin ti wọn ń wa kẹ̀kẹ́ lẹ́sẹ̀ mẹ́ta táa mọ̀ sí kẹ̀kẹ́ Márúwá jẹun sọ pé isẹ́ náà kò dí àwọn lọ́wọ́ iṣẹ́ ilé.

Awọ́n akinkanju obinrin to n wa ọkada ni ilu Eko ní isẹ́ náà pé ju kí èèyàn máa se òwò nàbì lọ.

Ọ̀kan nínú wọn ní àwọn tó ń bá oun wa kẹ̀kẹ́ náà tẹ́lẹ̀, kìí se sọ òtítọ́ ló mú kí òun máa wa kẹ̀kẹ́ náà fúnra ara òun.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: