Òwò Àdìrẹ bùyààrì ní Abẹ́òkúta
Òwò Àdìrẹ bùyààrì ní Abẹ́òkúta
Àwọn tí wọn ti pẹ́ níbi iṣẹ́ àdìrẹ ṣiṣe ṣàlàyé bí wọn ti ń ṣe é.
Wọ́n ní asọ tí a dì, tí a rẹ, ni wọ́n ń pè ní Àdìrẹ.
Wọ́n fi yé wa pé aleè fi aró, ìko, ẹ̀kọ, abẹ́rẹ́, àbẹ́là àti ẹ̀rọ ìgbálódé se Àdìrẹ.
Ìlú Kéǹta ní Ẹ̀gbá ni wọ́n ti ń se Àdìrẹ.