Àkókò márùún ninu ayé Winnie Madikizela-Mandela

Ìyàwó ògbóǹtarìgì olóṣèlú lorilẹede South Africa, Nelson Mandela, Winnie Mandẹla ti jalaisi lẹ́ni ọdún mọ̀kànlélọ́gọ́rin. Díẹ̀ ree lara awọn ìgbà aye rẹ̀.

Àkọlé àwòrán,

Winnie Mandela lasiko to n se ọjọ́ọ̀bí ọgọ́rin ọdún

Àkọlé àwòrán,

Àsìkò ti awọn ọlọ́pàá wa mu Winnie Mandela lori ẹsun pe o n tako ijọba apatheid

Àkọlé àwòrán,

Winnie Mandela lasiko to n kede wíwá sopin ìgbéyàwó rẹ̀ pẹ̀lú Nelson Mandela lọ́dún 1996

Àkọlé àwòrán,

Winnie Mandela n se idaro ọkọ rẹ Nelson Mandela

Àkọlé àwòrán,

Winnie Mandela ati Nelson Mandela pẹlu ọmọ-ọmọ wọn