Àwòrán ìgbésí ayé Winnie Madikizela-Mandela

Ìyàwó ògbóǹtarìgì olóṣèlú lorilẹede South Africa, Nelson Mandela, Winnie Mandẹla ti jalaisi lẹ́ni ọdún mọ̀kànlélọ́gọ́rin