Badagry, slave trade international day: Ojú ọ̀nà àrèmabọ̀ fáwọn ẹrú tó ń lọ sókè òkun
Badagry, slave trade international day: Ojú ọ̀nà àrèmabọ̀ fáwọn ẹrú tó ń lọ sókè òkun
Ibùdó ojú ọ̀nà àrèmabọ̀ tó wà ní ìlú Badagry rèé, tí áwọn òyìnbó ń kó áwọn ẹrú sí, láti lọ fi se iṣẹ́ agbára sókè òkun.
Ẹrúkẹ́rú tó bá ti dé ibùdó yìí kò tún padà sílé mọ́, ìpàdé di ọ̀hún ni.
Odò Gbeferu ni wọ́n ń pe odò ti wọn ń gbà láti kó ẹrú lọ sókè òkun.
BBC Yorùbá tún rí owó táwọn ẹrú yìí ń ná nígbà náà àti ẹ̀wọ̀n tí wọ́n ń so mọ́ wọn lẹ́sẹ̀ pẹ̀lú irin ọrùn wọn.