Ebenezer Obey: Ọjọ́ ìbí 76 tó ọpẹ́ fún Ọlọ́run

Ìlúmọ̀ọ́ká olórin jùjú nnì, Olóyè Ebenezer Fabiyi-Obey, lásìkò tó ń sọ̀rọ̀ lórí àyájọ́ ọjọ́ ìbí ọdun kẹ́rìndínlọ́gọ́rin rẹ̀ lókè èèpẹ̀ sàlàyé pé, Ọlọ́run ni òun yóò màá fi ìyókù ayé òun sìn lẹ́yìn ọdun kọkànlélọ́gọ́ta tí òun ti bẹ̀rẹ̀ isẹ́ orin kíkọ.

Ó wá dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ fún ìfẹ́ aláìlẹ́gbẹ́ tí wọn ń fún òun nítorípé ìfẹ́ wọn ló gbé òun sókè.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: