Màmá Boko Haram: Leah yóò padà sílé láì s‘éwu

Màmá Boko Haram: Leah yóò padà sílé láì s‘éwu

Aisha Wakil, táa mọ̀ sí Màmá Boko Haram ní Leah Sharibu yóò padà sílé láìpẹ̀.

Màmá Boko Haram fọwọ́ gbáyà bẹ́ẹ̀ lásìkò tó ń bá BBC sọ̀rọ̀.

O fi kún-un pé òun kò leè sàlàyé ìdí tí wọn kò tíì fi dáa sílẹ̀ báyìí.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: